1 Àwọn Ọba 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Sólómọ́nì fún Hírámù ní ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀* àlìkámà* kó lè jẹ́ oúnjẹ fún agbo ilé rẹ̀ àti ogún (20) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀ ògidì òróró ólífì.* Ohun tí Sólómọ́nì máa ń fún Hírámù nìyẹn lọ́dọọdún.+
11 Sólómọ́nì fún Hírámù ní ọ̀kẹ́ kan (20,000) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀* àlìkámà* kó lè jẹ́ oúnjẹ fún agbo ilé rẹ̀ àti ogún (20) òṣùwọ̀n kọ́ọ̀ ògidì òróró ólífì.* Ohun tí Sólómọ́nì máa ń fún Hírámù nìyẹn lọ́dọọdún.+