ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 13:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ẹ wò ó! Ọlọ́run tòótọ́ wà pẹ̀lú wa, ó ń darí wa. Àwọn àlùfáà rẹ̀ sì wà níbí láti máa fun kàkàkí láti fi pe ogun sí yín. Ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ má ṣe bá Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín jà, torí ẹ ò ní ṣàṣeyọrí.”+

  • 2 Kíróníkà 32:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 “Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára. Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà nítorí ọba Ásíríà+ àti gbogbo ọ̀pọ̀ èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀, torí àwọn tó wà pẹ̀lú wa pọ̀ ju àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀.+ 8 Agbára èèyàn ló gbẹ́kẹ̀ lé,* àmọ́ Jèhófà Ọlọ́run wa ló wà pẹ̀lú wa láti ràn wá lọ́wọ́, kó sì jà fún wa.”+ Ọ̀rọ̀ Hẹsikáyà ọba Júdà sì fún àwọn èèyàn náà lókun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́