ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 18:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àwọn ìlú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé nìyí: Jẹ́ríkò, Bẹti-hógílà, Emeki-késísì,

  • Jóṣúà 18:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Kefari-ámónì, Ófínì àti Gébà,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ ìlú méjìlá (12) pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.

  • 1 Kíróníkà 6:60
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 60 láti inú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì, Gébà+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Álémétì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Ánátótì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀. Gbogbo ìlú tí wọ́n fún ìdílé wọn jẹ́ mẹ́tàlá (13).+

  • 1 Kíróníkà 6:64
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 64 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú yìí pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko+ wọn nìyẹn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́