Sekaráyà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ta ló pẹ̀gàn ọjọ́ tí nǹkan bẹ̀rẹ̀ wẹ́rẹ́?*+ Inú wọn á dùn, wọ́n á sì rí okùn ìwọ̀n* ní ọwọ́ Serubábélì. Àwọn méje yìí ni ojú Jèhófà, tó ń wò káàkiri ayé.”+
10 Ta ló pẹ̀gàn ọjọ́ tí nǹkan bẹ̀rẹ̀ wẹ́rẹ́?*+ Inú wọn á dùn, wọ́n á sì rí okùn ìwọ̀n* ní ọwọ́ Serubábélì. Àwọn méje yìí ni ojú Jèhófà, tó ń wò káàkiri ayé.”+