1 Àwọn Ọba 15:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ní ti gbogbo ìyókù ìtàn Ásà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti àwọn ìlú tí ó kọ́,* ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? Àmọ́, nígbà tí ó darúgbó, àìsàn kan mú un ní ẹsẹ̀.+
23 Ní ti gbogbo ìyókù ìtàn Ásà àti gbogbo agbára rẹ̀ àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti àwọn ìlú tí ó kọ́,* ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? Àmọ́, nígbà tí ó darúgbó, àìsàn kan mú un ní ẹsẹ̀.+