2 Kíróníkà 14:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ásà ní àwọn ọmọ ogun tí wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (300,000) ọkùnrin láti Júdà, apata ńlá àti aṣóró wà lọ́wọ́ wọn. Ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlá (280,000) jagunjagun tó lákíkanjú láti inú Bẹ́ńjámínì ló ń gbé asà,* tí wọ́n sì ní ọfà lọ́wọ́.*+
8 Ásà ní àwọn ọmọ ogun tí wọ́n jẹ́ ọ̀kẹ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún (300,000) ọkùnrin láti Júdà, apata ńlá àti aṣóró wà lọ́wọ́ wọn. Ọ̀kẹ́ mẹ́rìnlá (280,000) jagunjagun tó lákíkanjú láti inú Bẹ́ńjámínì ló ń gbé asà,* tí wọ́n sì ní ọfà lọ́wọ́.*+