2 Kíróníkà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà fìdí ìjọba náà múlẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀;+ gbogbo Júdà ń mú ẹ̀bùn wá fún Jèhóṣáfátì, ó sì ní ọrọ̀ àti ògo tó pọ̀ gan-an.+
5 Jèhófà fìdí ìjọba náà múlẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀;+ gbogbo Júdà ń mú ẹ̀bùn wá fún Jèhóṣáfátì, ó sì ní ọrọ̀ àti ògo tó pọ̀ gan-an.+