-
1 Àwọn Ọba 14:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ní àkókò yẹn, Ábíjà ọmọkùnrin Jèróbóámù ń ṣàìsàn.
-
-
1 Àwọn Ọba 14:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Gbogbo Ísírẹ́lì á ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, wọ́n á sì sin ín, torí òun nìkan ni wọ́n máa sin sínú sàréè lára àwọn ará ilé Jèróbóámù, nítorí pé òun nìkan ni Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì rí ohun rere nínú rẹ̀ ní ilé Jèróbóámù.
-