Ìṣe 10:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ni Pétérù bá bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀, ó ní: “Ní báyìí, ó ti wá yé mi dáadáa pé Ọlọ́run kì í ṣe ojúsàájú,+ Róòmù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí kò sí ojúsàájú lọ́dọ̀ Ọlọ́run.+ 1 Pétérù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Tí ẹ bá sì ń ké pe Baba tó ń fi iṣẹ́ ọwọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan ṣèdájọ́ láìṣe ojúsàájú,+ ẹ máa fi ìbẹ̀rù hùwà+ ní àkókò tí ẹ fi jẹ́ olùgbé fún ìgbà díẹ̀.*
17 Tí ẹ bá sì ń ké pe Baba tó ń fi iṣẹ́ ọwọ́ ẹnì kọ̀ọ̀kan ṣèdájọ́ láìṣe ojúsàájú,+ ẹ máa fi ìbẹ̀rù hùwà+ ní àkókò tí ẹ fi jẹ́ olùgbé fún ìgbà díẹ̀.*