ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 11:27, 28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Mi ò ṣẹ̀ ọ́ rárá, ìwọ lo ṣe ohun tí kò dáa bí o ṣe wá gbógun jà mí. Kí Jèhófà Onídàájọ́+ ṣe ìdájọ́ lónìí láàárín àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn èèyàn Ámónì.’”

      28 Àmọ́ ọba àwọn ọmọ Ámónì kò fetí sí ohun tí Jẹ́fútà ní kí wọ́n sọ fún un.

  • Sáàmù 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Dìde nínú ìbínú rẹ, Jèhófà;

      Gbéra láti kojú àwọn ọ̀tá mi nínú ìbínú wọn;+

      Jí nítorí mi, kí o sì mú kí wọ́n ṣe ìdájọ́ òdodo.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́