-
1 Sámúẹ́lì 14:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Torí náà, Sọ́ọ̀lù àti gbogbo àwọn èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ kóra jọ, wọ́n sì jáde lọ sí ojú ogun náà, ibẹ̀ ni wọ́n ti rí i tí àwọn Filísínì dojú idà kọ ara wọn, ìdàrúdàpọ̀ náà sì pọ̀ gan-an.
-