-
1 Àwọn Ọba 22:41, 42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Jèhóṣáfátì+ ọmọ Ásà di ọba lórí Júdà ní ọdún kẹrin Áhábù ọba Ísírẹ́lì. 42 Ẹni ọdún márùndínlógójì (35) ni Jèhóṣáfátì nígbà tó jọba, ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ásúbà ọmọ Ṣílíháì.
-