-
1 Àwọn Ọba 15:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ásà ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Jèhófà,+ bíi Dáfídì baba ńlá rẹ̀.
-
-
2 Kíróníkà 14:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ásà ṣe ohun tó dára tó sì tọ́ ní ojú Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀.
-
-
2 Kíróníkà 14:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí náà, ó mú àwọn ibi gíga àti àwọn pẹpẹ tùràrí kúrò ní gbogbo àwọn ìlú Júdà,+ ìjọba náà sì wà láìsí ìyọlẹ́nu lábẹ́ àbójútó rẹ̀.
-