-
1 Kíróníkà 29:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Mo ti sa gbogbo ipá mi láti pèsè àwọn nǹkan sílẹ̀ fún ilé Ọlọ́run mi, mo ti pèsè wúrà fún iṣẹ́ ọnà wúrà, fàdákà fún iṣẹ́ ọnà fàdákà, bàbà fún iṣẹ́ ọnà bàbà, irin fún iṣẹ́ ọnà irin,+ àwọn igi fún iṣẹ́ ọnà igi,+ àwọn òkúta ónísì, àwọn òkúta tí wọ́n máa fi erùpẹ̀ tí a pò pọ̀ mọ, àwọn òkúta róbótó-róbótó lóríṣiríṣi àwọ̀, gbogbo oríṣiríṣi òkúta iyebíye àti òkúta alabásítà tó pọ̀ gan-an.
-