2 Àwọn Ọba 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní ọdún keje, Jèhóádà ránṣẹ́ sí àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún ẹ̀ṣọ́ Káríà àti àwọn ẹ̀ṣọ́ ààfin,*+ ó ní kí wọ́n wá bá òun ní ilé Jèhófà. Ó bá wọn ṣe àdéhùn,* ó sì ní kí wọ́n búra sí i ní ilé Jèhófà, lẹ́yìn náà ó fi ọmọ ọba hàn wọ́n.+
4 Ní ọdún keje, Jèhóádà ránṣẹ́ sí àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún ẹ̀ṣọ́ Káríà àti àwọn ẹ̀ṣọ́ ààfin,*+ ó ní kí wọ́n wá bá òun ní ilé Jèhófà. Ó bá wọn ṣe àdéhùn,* ó sì ní kí wọ́n búra sí i ní ilé Jèhófà, lẹ́yìn náà ó fi ọmọ ọba hàn wọ́n.+