2 Àwọn Ọba 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ni àlùfáà Jèhóádà bá gbé àpótí kan,+ ó lu ihò sí ọmọrí rẹ̀, ó sì gbé e sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ lápá ọ̀tún téèyàn bá wọ inú ilé Jèhófà. Ibẹ̀ ni àwọn àlùfáà tó ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà máa ń kó gbogbo owó tí àwọn èèyàn bá mú wá sí ilé Jèhófà sí.+
9 Ni àlùfáà Jèhóádà bá gbé àpótí kan,+ ó lu ihò sí ọmọrí rẹ̀, ó sì gbé e sí ẹ̀gbẹ́ pẹpẹ lápá ọ̀tún téèyàn bá wọ inú ilé Jèhófà. Ibẹ̀ ni àwọn àlùfáà tó ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà máa ń kó gbogbo owó tí àwọn èèyàn bá mú wá sí ilé Jèhófà sí.+