1 Àwọn Ọba 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Gígùn yàrá inú lọ́hùn-ún náà jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́;+ ó sì fi ògidì wúrà bò ó; ó fi igi kédárì bo pẹpẹ náà.+
20 Gígùn yàrá inú lọ́hùn-ún náà jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ogún (20) ìgbọ̀nwọ́;+ ó sì fi ògidì wúrà bò ó; ó fi igi kédárì bo pẹpẹ náà.+