2 Kíróníkà 23:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nígbà náà, wọ́n mú ọmọ ọba+ jáde, wọ́n sì fi adé* dé e, wọ́n fi Ẹ̀rí*+ sí i lórí, wọ́n fi jọba, Jèhóádà àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì fòróró yàn án. Wọ́n sọ pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”+
11 Nígbà náà, wọ́n mú ọmọ ọba+ jáde, wọ́n sì fi adé* dé e, wọ́n fi Ẹ̀rí*+ sí i lórí, wọ́n fi jọba, Jèhóádà àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì fòróró yàn án. Wọ́n sọ pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”+