ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 9:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Yàtọ̀ sí ìyẹn, èmi yóò béèrè ẹ̀jẹ̀ yín tó jẹ́ ẹ̀mí yín* pa dà. Èmi yóò béèrè lọ́wọ́ gbogbo ohun alààyè; ọwọ́ kálukú ni màá sì ti béèrè ẹ̀mí arákùnrin rẹ̀.+

  • Sáàmù 94:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 94 Jèhófà, Ọlọ́run ẹ̀san,+

      Ìwọ Ọlọ́run ẹ̀san, máa tàn yanran!

  • Jeremáyà 11:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ṣùgbọ́n Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ń fi òdodo ṣe ìdájọ́;

      Ó ń ṣàyẹ̀wò èrò inú* àti ọkàn.+

      Jẹ́ kí n rí ẹ̀san rẹ lára wọn,

      Nítorí ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹjọ́ mi lé.

  • Hébérù 10:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Torí a mọ Ẹni tó sọ pé: “Tèmi ni ẹ̀san; màá gbẹ̀san.” Àti pé: “Jèhófà* máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́