2 Àwọn Ọba 12:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́, àwọn ìránṣẹ́ Jèhóáṣì dìtẹ̀ mọ́ ọn,+ wọ́n sì pa á ní ilé Òkìtì,*+ ní ọ̀nà tó lọ sí Síílà.