6 Nígbà náà, àwọn àlùfáà gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà wá sí àyè rẹ̀,+ ní yàrá inú lọ́hùn-ún ilé náà, ìyẹn Ibi Mímọ́ Jù Lọ, wọ́n gbé e sí abẹ́ ìyẹ́ apá àwọn kérúbù.+
18 Ó tún fún un ní ìwọ̀n wúrà tí a yọ́ mọ́ fún pẹpẹ tùràrí+ àti fún àwòrán kẹ̀kẹ́ ẹṣin,+ ìyẹn, àwọn kérúbù+ wúrà tí wọ́n na ìyẹ́ apá wọn bo orí àpótí májẹ̀mú Jèhófà.