Àìsáyà 30:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’ Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+ Ọ̀rọ̀ dídùn* ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+
10 Wọ́n ń sọ fún àwọn aríran pé, ‘Ẹ má ṣe ríran,’ Àti fún àwọn olùríran pé, ‘Ẹ má sọ àwọn ìran tó jẹ́ òótọ́ fún wa.+ Ọ̀rọ̀ dídùn* ni kí ẹ bá wa sọ; ìran ẹ̀tàn ni kí ẹ máa rí.+