-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
Jóṣúà 15:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 láti Ẹ́kírónì sí apá ìwọ̀ oòrùn, gbogbo ibi tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Áṣídódì pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.
-
-
1 Sámúẹ́lì 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà tí àwọn Filísínì gba Àpótí+ Ọlọ́run tòótọ́, wọ́n gbé e láti Ẹbinísà wá sí Áṣídódì.
-