Nọ́ńbà 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìkùukùu wá kúrò lórí àgọ́ náà, wò ó! ẹ̀tẹ̀ tó funfun bíi yìnyín+ sì bo Míríámù. Ni Áárónì bá yíjú sọ́dọ̀ Míríámù, ó sì rí i pé ẹ̀tẹ̀+ ti bò ó. 2 Àwọn Ọba 5:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní báyìí, ẹ̀tẹ̀ Náámánì+ yóò lẹ̀ mọ́ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ rẹ títí láé.” Lójú ẹsẹ̀, ó di adẹ́tẹ̀, ẹ̀tẹ̀ rẹ̀ funfun bíi yìnyín,+ ó sì jáde kúrò níwájú rẹ̀.
10 Ìkùukùu wá kúrò lórí àgọ́ náà, wò ó! ẹ̀tẹ̀ tó funfun bíi yìnyín+ sì bo Míríámù. Ni Áárónì bá yíjú sọ́dọ̀ Míríámù, ó sì rí i pé ẹ̀tẹ̀+ ti bò ó.
27 Ní báyìí, ẹ̀tẹ̀ Náámánì+ yóò lẹ̀ mọ́ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ rẹ títí láé.” Lójú ẹsẹ̀, ó di adẹ́tẹ̀, ẹ̀tẹ̀ rẹ̀ funfun bíi yìnyín,+ ó sì jáde kúrò níwájú rẹ̀.