ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 7:23-26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Lẹ́yìn náà, ó fi irin ṣe Òkun.*+ Ó rí ribiti, fífẹ̀ ẹnu rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá, gíga rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún, okùn ìdíwọ̀n ọgbọ̀n (30) ìgbọ̀nwọ́ ló sì lè yí i ká.*+ 24 Àwọn iṣẹ́ ọnà tó rí bí akèrègbè+ wà nísàlẹ̀ ẹnu rẹ̀ yí ká, mẹ́wàá nínú ìgbọ̀nwọ́ kan, wọ́n yí Òkun náà po, ìlà méjì àwọn iṣẹ́ ọnà tó rí bí akèrègbè náà ni ó ṣe mọ́ ọn lára. 25 Wọ́n gbé Òkun náà ka orí akọ màlúù méjìlá (12),+ mẹ́ta dojú kọ àríwá, mẹ́ta dojú kọ ìwọ̀ oòrùn, mẹ́ta dojú kọ gúúsù, mẹ́ta sì dojú kọ ìlà oòrùn; Òkun náà wà lórí wọn, gbogbo wọn sì kọ̀dí sí abẹ́ Òkun náà. 26 Ìnípọn rẹ̀ jẹ́ ìbú ọwọ́ kan;* ẹnu rẹ̀ sì dà bí ẹnu ife, bí ìtànná òdòdó lílì. Ẹgbẹ̀rún méjì (2,000) báàtì* ni ó ń gbà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́