2 Kíróníkà 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Agbára Jèhóṣáfátì ń pọ̀ sí i,+ ó sì ń kọ́ àwọn ibi olódi+ àti àwọn ìlú tó ń kó nǹkan pa mọ́ sí+ ní Júdà.
12 Agbára Jèhóṣáfátì ń pọ̀ sí i,+ ó sì ń kọ́ àwọn ibi olódi+ àti àwọn ìlú tó ń kó nǹkan pa mọ́ sí+ ní Júdà.