-
Léfítíkù 25:46Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
46 Ẹ lè jẹ́ kí àwọn ọmọ yín jogún wọn kí wọ́n lè di ohun ìní wọn títí láé. Ẹ lè lò wọ́n bí òṣìṣẹ́, àmọ́ ẹ má fi ọwọ́ líle mú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tó jẹ́ arákùnrin yín.+
-