-
2 Kíróníkà 28:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Bákan náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mú ọ̀kẹ́ mẹ́wàá (200,000) lára àwọn arákùnrin wọn lẹ́rú, àwọn obìnrin, àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin; wọ́n tún gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹrù, wọ́n sì kó àwọn ẹrù náà wá sí Samáríà.+
-