-
2 Àwọn Ọba 16:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí náà, Áhásì rán àwọn òjíṣẹ́ sí Tigilati-pílésà+ ọba Ásíríà, ó ní: “Ìránṣẹ́ rẹ ni mí, ọmọ rẹ sì ni mo jẹ́. Wá gbà mí lọ́wọ́ ọba Síríà àti lọ́wọ́ ọba Ísírẹ́lì tí wọ́n ń gbéjà kò mí.” 8 Áhásì wá kó fàdákà àti wúrà tí wọ́n rí ní ilé Jèhófà àti ní àwọn ibi ìṣúra ilé* ọba, ó sì fi àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ránṣẹ́ sí ọba Ásíríà.+
-