2 Àwọn Ọba 16:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Yàtọ̀ síyẹn, Ọba Áhásì gé àwọn iṣẹ́ ọnà pẹlẹbẹ-pẹlẹbẹ+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù sí wẹ́wẹ́, ó sì gbé bàsíà kúrò lórí àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù náà,+ ó sọ Òkun kalẹ̀ lórí àwọn akọ màlúù+ tó gbé e dúró, ó sì gbé e sórí ibi tí a fi òkúta tẹ́.+
17 Yàtọ̀ síyẹn, Ọba Áhásì gé àwọn iṣẹ́ ọnà pẹlẹbẹ-pẹlẹbẹ+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù sí wẹ́wẹ́, ó sì gbé bàsíà kúrò lórí àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù náà,+ ó sọ Òkun kalẹ̀ lórí àwọn akọ màlúù+ tó gbé e dúró, ó sì gbé e sórí ibi tí a fi òkúta tẹ́.+