-
1 Kíróníkà 25:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Gbogbo wọn jẹ́ ọmọ Hémánì, aríran ọba tó bá ti kan ohun tó jẹ mọ́ Ọlọ́run tòótọ́ láti gbé e* ga; torí náà, Ọlọ́run tòótọ́ fún Hémánì ní ọmọkùnrin mẹ́rìnlá (14) àti ọmọbìnrin mẹ́ta.
-