-
2 Kíróníkà 30:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ọ̀pọ̀ lára àwọn tó wà ní ìjọ náà ni kò tíì ya ara wọn sí mímọ́, àwọn ọmọ Léfì ló sì ń bójú tó pípa àwọn ẹran ẹbọ Ìrékọjá fún gbogbo àwọn tí kò mọ́,+ láti yà wọ́n sí mímọ́ fún Jèhófà.
-