2 Àmọ́, ọba àti àwọn ìjòyè rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo àwọn èèyàn ní Jerúsálẹ́mù pinnu láti ṣe Ìrékọjá náà ní oṣù kejì,+ 3 nítorí wọn ò lè ṣe é ní àkókò tó yẹ kí wọ́n ṣe é,+ torí pé àwọn àlùfáà tó ti ya ara wọn sí mímọ́ kò pọ̀ tó + àti pé àwọn èèyàn náà kò tíì kóra jọ sí Jerúsálẹ́mù.