ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 11:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Àwọn ọmọ Léfì fi àwọn ibi ìjẹko wọn àti ohun ìní wọn sílẹ̀,+ wọ́n wá sí Júdà àti Jerúsálẹ́mù, torí pé Jèróbóámù àti àwọn ọmọ rẹ̀ ti lé wọn kúrò lẹ́nu iṣẹ́ àlùfáà fún Jèhófà.+

  • 2 Kíróníkà 11:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn tó wá láti gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì tí wọ́n ti pinnu láti máa wá Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì tẹ̀ lé àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì wá sí Jerúsálẹ́mù láti rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́