ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 35:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Jòsáyà fún àwọn èèyàn náà ní agbo ẹran, akọ ọ̀dọ́ àgùntàn àti akọ ọmọ ewúrẹ́, láti fi ṣe ẹran Ìrékọjá fún gbogbo àwọn tó wá, àpapọ̀ rẹ̀ jẹ́ ọ̀kẹ́ kan ààbọ̀ (30,000), ó tún fi ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) màlúù kún un. Inú ohun ìní ọba ni àwọn nǹkan yìí ti wá.+ 8 Àwọn ìjòyè rẹ̀ tún fún àwọn èèyàn náà àti àwọn àlùfáà pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì ní ọrẹ àtinúwá. Hilikáyà,+ Sekaráyà àti Jéhíélì, àwọn aṣáájú ilé Ọlọ́run tòótọ́, fún àwọn àlùfáà ní ẹgbẹ̀rún méjì ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (2,600) ẹran Ìrékọjá àti ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) màlúù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́