ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Kírúsì ọba Páṣíà kó wọn jáde lábẹ́ àbójútó Mítírédátì, ẹni tó ń tọ́jú ìṣúra, ó sì ka iye wọn fún Ṣẹṣibásà*+ ìjòyè Júdà.

  • Ẹ́sírà 1:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbogbo àwọn nǹkan èlò wúrà àti ti fàdákà jẹ́ ẹgbẹ̀rún márùn-ún ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (5,400). Gbogbo nǹkan yìí ni Ṣẹṣibásà kó wá nígbà tí wọ́n kó àwọn tó wà nígbèkùn+ kúrò ní Bábílónì wá sí Jerúsálẹ́mù.

  • Hágáì 1:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Torí náà, Jèhófà ru ẹ̀mí+ Serubábélì ọmọ Ṣéálítíẹ́lì, gómìnà Júdà+ sókè, ó tún ru ẹ̀mí Jóṣúà+ ọmọ Jèhósádákì, àlùfáà àgbà sókè àti ẹ̀mí gbogbo àwọn tó ṣẹ́ kù nínú àwọn èèyàn náà; wọ́n wá, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe àtúnkọ́ ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tó jẹ́ Ọlọ́run wọn.+

  • Mátíù 1:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Lẹ́yìn tí wọ́n kó wọn lọ sí Bábílónì, Jekonáyà bí Ṣéálítíẹ́lì;

      Ṣéálítíẹ́lì bí Serubábélì;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́