-
Ẹ́kísódù 27:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Kí o pàṣẹ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n gbé ògidì òróró ólífì tí wọ́n fún wá sọ́dọ̀ rẹ láti máa fi tan iná, kí àwọn fìtílà náà lè máa wà ní títàn nígbà gbogbo.+
-
-
Léfítíkù 2:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “‘Tí o bá fẹ́ fi ohun tí wọ́n yan nínú ààrò ṣe ọrẹ ọkà, kó jẹ́ èyí tí wọ́n fi ìyẹ̀fun tó kúnná ṣe, búrẹ́dì aláìwú tí wọ́n fi òróró pò, tó rí bí òrùka tàbí búrẹ́dì aláìwú pẹlẹbẹ tí wọ́n fi òróró pa.+
-