Hágáì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Ẹ gun orí òkè lọ, kí ẹ sì gbé igi gẹdú wá.+ Kí ẹ sì kọ́ ilé náà,+ kí inú mi lè dùn sí i, kí a sì lè yìn mí lógo,’+ ni Jèhófà wí.”
8 “‘Ẹ gun orí òkè lọ, kí ẹ sì gbé igi gẹdú wá.+ Kí ẹ sì kọ́ ilé náà,+ kí inú mi lè dùn sí i, kí a sì lè yìn mí lógo,’+ ni Jèhófà wí.”