-
Ẹ́sírà 6:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Kí Ọlọ́run tó mú kí orúkọ rẹ̀ máa wà níbẹ̀+ gbá ọba tàbí èèyàn èyíkéyìí dà nù tí ó bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè láti rú òfin yìí, tí ó sì ba ilé Ọlọ́run yẹn jẹ́, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù. Èmi, Dáríúsì ló pa àṣẹ yìí. Kí ẹ ṣe ohun tí mo sọ ní kánmọ́kánmọ́.”
-