Ẹ́kísódù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Wò ó, mo ti mú kí o dà bí Ọlọ́run* fún Fáráò, Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ yóò sì di wòlíì rẹ.+ Ẹ́kísódù 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+
7 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Wò ó, mo ti mú kí o dà bí Ọlọ́run* fún Fáráò, Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ yóò sì di wòlíì rẹ.+
28 “Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+