ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́sírà 6:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “Ní ọdún kìíní Ọba Kírúsì, Ọba Kírúsì pa àṣẹ kan nípa ilé Ọlọ́run ní Jerúsálẹ́mù, ó ní:+ ‘Ẹ tún ilé náà kọ́ kí ẹ lè máa rú àwọn ẹbọ níbẹ̀, kí ẹ sì fi àwọn ìpìlẹ̀ rẹ̀ lélẹ̀ sí àyè rẹ̀; kí gíga rẹ̀ jẹ́ ọgọ́ta (60) ìgbọ̀nwọ́,* kí fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ọgọ́ta (60) ìgbọ̀nwọ́,+ 4 kí ó ní ipele mẹ́ta òkúta ńlá tí wọ́n yí sí àyè wọn àti ipele kan ẹ̀là gẹdú;+ kí owó tí wọ́n máa fi ṣe é sì wá láti ilé ọba.+

  • Ẹ́sírà 6:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Yàtọ̀ síyẹn, mo pàṣẹ ohun tí ẹ máa ṣe fún àwọn àgbààgbà Júù, kí wọ́n lè tún ilé Ọlọ́run kọ́, àṣẹ náà nìyí: Látinú ibi ìṣúra ọba,+ ìyẹn látinú owó orí tí ẹ gbà láti agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò ni kí ẹ ti máa fún àwọn ọkùnrin náà lówó tí wọ́n á fi ṣe iṣẹ́ náà, ẹ má sì fi falẹ̀, kí wọ́n lè máa bá iṣẹ́ náà lọ láìsí ìdíwọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́