1 Kíróníkà 9:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn tó kọ́kọ́ pa dà sídìí ohun ìní wọn, ní àwọn ìlú wọn, ni àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì.*+
2 Àwọn tó kọ́kọ́ pa dà sídìí ohun ìní wọn, ní àwọn ìlú wọn, ni àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì.*+