Ẹ́sírà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì,+ àwọn akọrin,+ àwọn aṣọ́bodè+ àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ lọ sí Jerúsálẹ́mù ní ọdún keje Ọba Atasásítà.
7 Àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì,+ àwọn akọrin,+ àwọn aṣọ́bodè+ àti àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì*+ lọ sí Jerúsálẹ́mù ní ọdún keje Ọba Atasásítà.