1 Kíróníkà 6:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ* Ámúrámù+ ni Áárónì,+ Mósè+ àti Míríámù.+ Àwọn ọmọ Áárónì sì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+ 4 Élíásárì bí Fíníhásì;+ Fíníhásì bí Ábíṣúà.
3 Àwọn ọmọ* Ámúrámù+ ni Áárónì,+ Mósè+ àti Míríámù.+ Àwọn ọmọ Áárónì sì ni Nádábù, Ábíhù,+ Élíásárì+ àti Ítámárì.+ 4 Élíásárì bí Fíníhásì;+ Fíníhásì bí Ábíṣúà.