Ẹ́kísódù 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.
23 Áárónì wá fi Élíṣébà, ọmọ Ámínádábù, arábìnrin Náṣónì+ ṣe aya. Ó bí Nádábù, Ábíhù, Élíásárì àti Ítámárì+ fún un.