ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nehemáyà 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Apá tó tẹ̀ lé tiwọn ni Mérémótì + ọmọ Úríjà ọmọ Hákósì ti ṣe iṣẹ́ àtúnṣe, Méṣúlámù+ ọmọ Berekáyà ọmọ Meṣesábélì sì ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tiwọn, bákan náà Sádókù ọmọ Béánà ṣe iṣẹ́ àtúnṣe ní apá tó tẹ̀ lé tiwọn.

  • Nehemáyà 3:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Lẹ́yìn rẹ̀, Mérémótì+ ọmọ Úríjà ọmọ Hákósì tún ẹ̀ka míì ṣe, láti ẹnu ọ̀nà ilé Élíáṣíbù títí dé òpin ilé Élíáṣíbù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́