Nehemáyà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tó tẹ̀ lé Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì+ àti Jéṣúà+ nìyí: Seráyà, Jeremáyà, Ẹ́sírà, Nehemáyà 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọmọ Léfì ni Jéṣúà, Bínúì, Kádímíélì,+ Ṣerebáyà, Júdà àti Matanáyà + tó ń gbé orin ọpẹ́ pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀.
12 Àwọn àlùfáà àti àwọn ọmọ Léfì tó tẹ̀ lé Serubábélì+ ọmọ Ṣéálítíẹ́lì+ àti Jéṣúà+ nìyí: Seráyà, Jeremáyà, Ẹ́sírà,
8 Àwọn ọmọ Léfì ni Jéṣúà, Bínúì, Kádímíélì,+ Ṣerebáyà, Júdà àti Matanáyà + tó ń gbé orin ọpẹ́ pẹ̀lú àwọn arákùnrin rẹ̀.