Ẹ́sírà 7:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Kí o tètè fi owó yìí ra àwọn akọ màlúù,+ àwọn àgbò+ àti àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn+ pẹ̀lú àwọn ohun tí wọ́n nílò fún ọrẹ ọkà+ àti ọrẹ ohun mímu,+ kí o sì fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ ilé Ọlọ́run yín, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù.
17 Kí o tètè fi owó yìí ra àwọn akọ màlúù,+ àwọn àgbò+ àti àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn+ pẹ̀lú àwọn ohun tí wọ́n nílò fún ọrẹ ọkà+ àti ọrẹ ohun mímu,+ kí o sì fi wọ́n rúbọ lórí pẹpẹ ilé Ọlọ́run yín, èyí tó wà ní Jerúsálẹ́mù.