Ẹ́sírà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nígbà náà, Táténáì gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò àti Ṣetari-bósénáì+ pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, ṣe gbogbo ohun tí Ọba Dáríúsì pa láṣẹ ní kánmọ́kánmọ́.
13 Nígbà náà, Táténáì gómìnà agbègbè tó wà ní Ìkọjá Odò àti Ṣetari-bósénáì+ pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn, ṣe gbogbo ohun tí Ọba Dáríúsì pa láṣẹ ní kánmọ́kánmọ́.