-
Ẹ́sírà 9:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Gbàrà tí a parí àwọn nǹkan yìí, àwọn olórí wá bá mi, wọ́n sì sọ pé: “Àwọn èèyàn Ísírẹ́lì àti àwọn àlùfáà pẹ̀lú àwọn ọmọ Léfì kò ya ara wọn sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn èèyàn àwọn ilẹ̀ tó yí wọn ká àti àwọn ohun ìríra wọn,+ ìyẹn àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Pérísì, àwọn ará Jébúsì, àwọn ọmọ Ámónì, àwọn ọmọ Móábù, àwọn ará Íjíbítì+ àti àwọn Ámórì. +
-